Tope Alabi SongsTY Bello Songs

Iwo Lawa O Ma Bo – Tope Alabi & TY Bello (Mp3, Video and Lyrics)

Iwo Lawa O Ma Bo mp3 Download by Tope Alabi & TY Bello.

Nigerian veteran gospel singers Tope Alabi & TY Bello releases a brand new tune, “Iwo Lawa O Ma Bo”.

Related Articles

Download Iwo Lawa O Ma Bo by Tope Alabi & TY Bello

Iwo Lawa O Ma Bo Lyrics by Tope Alabi & TY Bello

Wa Ma gbemi mi ninu

Wa Ma gbemi mi ninu
Wa Ma gbemi lokan
Wa Ma gami googo bi eni mutin olowo nla

Wa Ma romi siwaju
Romi so eyin to nri mo ndun ninu ree
Kabiyesi, olowo orimi oooo

Wa Ma gbemi ninu se
Wa Ma gbe wa lokan
Iwo loni ayo to kun inu wa
Wa Ma gbemi ninu

Wa Ma gbe wa ninu Wa Ma ti wa googo
Ti wa googo

Kin se bi eni fe subu
Sugbon bi eni fe dunnu
Idunu wa lo po ninu ree
Ayo igbala ree kun inu waa

Kabiyesi oo awa Ma gbe oo ga

Iwo to poo ni ipa ati agbara
Iwo lawa wa gba ga

Oni bi se bi, awa o dasi
Iwo nikan lawa mo
Awon taya won se tiwo
Iwo nikan lawa mo se

Ajewo re
Aka gbogbo aye wa soke
Ani iwo lawa O si titi dale
Lojo opotutu

Dojo opotutu
Olu Bo Bo Bo Bo
Iwo la o ma bo

Bo Bo Bo Bo Bo Bo o
Bo bo Aye
Bo bo orun
Bo bo awon angeli
Bo bo eda orun
Bo bo agbagba meri dilogun
Iwo lawa o ma bo

Bo bo
Bo bo bo
Olu Bo
Iwo ni

Iwo l’Olu bo
Iwo lawa o ma bo

Iwo lami o ma bo
Iwo Lawa O Ma Bo
Iwo lami o ma bo
Iwo Lawa O Ma Bo

Iwo lami o ma bo
Iwo Lawa O Ma Bo
Iwo lami o ma bo
Iwo Lawa O Ma Bo

Iwo lami o ma bo
Iwo Lawa O Ma Bo

(Adlibs)
Resp: Iwo Lawa O Ma Bo

Iwo, Iwo
Iwo Lawa O Ma Bo
Iwo, Iwo
Iwo Lawa O Ma Bo

Iwo, Iwo
Iwo Lawa O Ma Bo
Iwo, Iwo
Iwo Lawa O Ma Bo

Iwo, Iwo
Iwo Lawa O Ma Bo
Iwo, Iwo
Iwo Lawa O Ma Bo

Bo Bo bo
Iwo Lawa O Ma Bo
Bo Bo bo tiri
Iwo Lawa O Ma Bo

(Adlibs)
Resp: Iwo Lawa O Ma Bo

Recommended for you

Awa Gbe O Ga – Tope Alabi & TY Bello (Audio, Video and Lyrics)

Tope Alabi – Agbara Nla Ft. Iseoluwa (Mp3, Video and Lyrics)

Orile Ede Mi (My Country) – Tope Alabi (Mp3, Video and Lyrics)

Trillertunes

Nigerian Top User-friendly Music & Entertainment Website. Follow Us On all our Social media handles.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

Back to top button