Tope Alabi Songs

Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise (Mp3, Lyrics)

Loro Lero Ati Nise mp3 Download by Tope Alabi

Nigerian veteran gospel songstress Tope Alabi release a brand new song, “Loro Lero Ati Nise“. off her Hymnal Vol. 1 Album.

Related Articles

Download Loro Lero Ati Nise mp3 by Tope Alabi

Video: Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi

Loro Lero Ati Nise Lyrics by Tope Alabi

[Verse 1]
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

[Chrous]
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

[Verse 2]
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

[Verse 3]
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise

Recommended for you

Tope Alabi – Imole De Ft. TY Bello & George

Tope Alabi – Talo Dabi Re (Mp3 and Lyrics)

Tope Alabi – You Are Worthy (Mp3, Lyrics, Video)

Trillertunes

Nigerian Top User-friendly Music & Entertainment Website. Follow Us On all our Social media handles.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

Back to top button